-
Òwe 6:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Ìgbà wo ni ìwọ ọ̀lẹ máa dùbúlẹ̀ dà?
Ìgbà wo lo máa dìde lójú oorun rẹ?
-
-
Òwe 24:33, 34Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
33 Oorun díẹ̀, ìtòògbé díẹ̀,
Kíkáwọ́ gbera díẹ̀ láti sinmi,
34 Ipò òṣì rẹ yóò sì dé bí olè,
Àti àìní rẹ bí ọkùnrin tó dìhámọ́ra.+
-