Sáàmù 19:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Àwọn ìtọ́sọ́nà látọ̀dọ̀ Jèhófà jẹ́ òdodo, wọ́n ń mú ọkàn yọ̀;+Àṣẹ Jèhófà mọ́, ó ń mú kí ojú mọ́lẹ̀.+ Sáàmù 19:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 A ti fi wọ́n kìlọ̀ fún ìránṣẹ́ rẹ;+Èrè ńlá wà nínú pípa wọ́n mọ́.+ Òwe 13:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ẹni tí kò bá ka ìbáwí sí á di òtòṣì, á sì kan àbùkù,Àmọ́ ẹni tó bá ń gba ìtọ́sọ́nà* ni a ó gbé ga.+
8 Àwọn ìtọ́sọ́nà látọ̀dọ̀ Jèhófà jẹ́ òdodo, wọ́n ń mú ọkàn yọ̀;+Àṣẹ Jèhófà mọ́, ó ń mú kí ojú mọ́lẹ̀.+
18 Ẹni tí kò bá ka ìbáwí sí á di òtòṣì, á sì kan àbùkù,Àmọ́ ẹni tó bá ń gba ìtọ́sọ́nà* ni a ó gbé ga.+