Òwe 24:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Lọ́nà kan náà, mọ̀ pé ọgbọ́n dára fún ọ.*+ Tí o bá wá a rí, ọjọ́ ọ̀la rẹ á dáraÌrètí rẹ kò sì ní pa rẹ́.+
14 Lọ́nà kan náà, mọ̀ pé ọgbọ́n dára fún ọ.*+ Tí o bá wá a rí, ọjọ́ ọ̀la rẹ á dáraÌrètí rẹ kò sì ní pa rẹ́.+