Sáàmù 19:9, 10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ìbẹ̀rù Jèhófà+ mọ́, ó wà títí láé. Àwọn ìdájọ́ Jèhófà jẹ́ òótọ́, òdodo ni wọ́n látòkè délẹ̀.+ 10 Wọ́n yẹ ní fífẹ́ ju wúrà,Ju ọ̀pọ̀ wúrà tó dáa,*+Wọ́n sì dùn ju oyin lọ,+ oyin inú afárá. Sáàmù 119:103 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 103 Àwọn ọ̀rọ̀ rẹ mà dùn mọ́ òkè ẹnu mi o,Ó dùn ju oyin lọ lẹ́nu mi!+
9 Ìbẹ̀rù Jèhófà+ mọ́, ó wà títí láé. Àwọn ìdájọ́ Jèhófà jẹ́ òótọ́, òdodo ni wọ́n látòkè délẹ̀.+ 10 Wọ́n yẹ ní fífẹ́ ju wúrà,Ju ọ̀pọ̀ wúrà tó dáa,*+Wọ́n sì dùn ju oyin lọ,+ oyin inú afárá.