Òwe 3:11, 12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ọmọ mi, má ṣe kọ ìbáwí Jèhófà,+Má sì kórìíra ìtọ́sọ́nà rẹ̀,+12 Torí pé àwọn tí Jèhófà nífẹ̀ẹ́ ló máa ń bá wí,+Bí bàbá ṣe máa ń fún ọmọ tí inú rẹ̀ dùn sí ní ìbáwí.+
11 Ọmọ mi, má ṣe kọ ìbáwí Jèhófà,+Má sì kórìíra ìtọ́sọ́nà rẹ̀,+12 Torí pé àwọn tí Jèhófà nífẹ̀ẹ́ ló máa ń bá wí,+Bí bàbá ṣe máa ń fún ọmọ tí inú rẹ̀ dùn sí ní ìbáwí.+