-
1 Àwọn Ọba 3:11, 12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Ọlọ́run wá sọ fún un pé: “Nítorí o kò béèrè ẹ̀mí gígùn* fún ara rẹ tàbí ọrọ̀ tàbí ikú* àwọn ọ̀tá rẹ, àmọ́ o béèrè òye láti máa gbọ́ àwọn ẹjọ́,+ 12 màá ṣe ohun tí o béèrè.+ Màá fún ọ ní ọkàn ọgbọ́n àti òye,+ tó fi jẹ́ pé bí kò ṣe sí ẹni tó dà bí rẹ ṣáájú, bẹ́ẹ̀ ni kò ní sí ẹni tó máa dà bí rẹ mọ́.+
-
-
2 Tímótì 2:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Máa ronú nígbà gbogbo lórí àwọn ohun tí mò ń sọ; Olúwa máa fún ọ ní òye* nínú ohun gbogbo.
-