Òwe 24:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ọgbọ́n la fi ń gbé ilé* ró,+Òye sì la fi ń fìdí rẹ̀ múlẹ̀. Òwe 31:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Tó bá la ẹnu rẹ̀, ọ̀rọ̀ ọgbọ́n ló ń jáde,+Òfin inú rere* sì wà ní ahọ́n rẹ̀.