-
Nehemáyà 6:2, 3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 ẹsẹ̀kẹsẹ̀ ni Sáńbálátì àti Géṣémù ránṣẹ́ sí mi pé: “Wá, jẹ́ ká dá ìgbà tí a jọ máa pàdé ní àwọn abúlé tó wà ní Pẹ̀tẹ́lẹ̀ Ónò.”+ Àmọ́ ṣe ni wọ́n ń gbèrò láti ṣe mí ní ibi. 3 Torí náà, mo rán àwọn òjíṣẹ́ sí wọn pé: “Iṣẹ́ ńlá ni mò ń ṣe, mi ò sì lè wá. Ṣé ó yẹ kí iṣẹ́ náà dúró torí pé mo fi í sílẹ̀ láti wá bá yín?”
-