Òwe 18:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Orúkọ Jèhófà jẹ́ ilé gogoro tó lágbára.+ Olódodo sá wọ inú rẹ̀, ó sì rí ààbò.*+ Àìsáyà 26:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ẹ lọ, ẹ̀yin èèyàn mi, ẹ wọnú yàrá yín tó wà ní inú,Kí ẹ sì ti àwọn ilẹ̀kùn yín mọ́ ara yín.+ Ẹ fi ara yín pa mọ́ fúngbà díẹ̀,Títí ìbínú* náà fi máa kọjá lọ.+ Hébérù 11:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ìgbàgbọ́ mú kí Nóà + fi ìbẹ̀rù Ọlọ́run hàn, lẹ́yìn tó gba ìkìlọ̀ láti ọ̀run nípa àwọn ohun tí a kò tíì rí,+ ó kan ọkọ̀ áàkì+ kí agbo ilé rẹ̀ lè rí ìgbàlà; ó dá ayé lẹ́bi nípasẹ̀ ìgbàgbọ́ yìí,+ ó sì di ajogún òdodo irú èyí tí ìgbàgbọ́ ń mú wá.
20 Ẹ lọ, ẹ̀yin èèyàn mi, ẹ wọnú yàrá yín tó wà ní inú,Kí ẹ sì ti àwọn ilẹ̀kùn yín mọ́ ara yín.+ Ẹ fi ara yín pa mọ́ fúngbà díẹ̀,Títí ìbínú* náà fi máa kọjá lọ.+
7 Ìgbàgbọ́ mú kí Nóà + fi ìbẹ̀rù Ọlọ́run hàn, lẹ́yìn tó gba ìkìlọ̀ láti ọ̀run nípa àwọn ohun tí a kò tíì rí,+ ó kan ọkọ̀ áàkì+ kí agbo ilé rẹ̀ lè rí ìgbàlà; ó dá ayé lẹ́bi nípasẹ̀ ìgbàgbọ́ yìí,+ ó sì di ajogún òdodo irú èyí tí ìgbàgbọ́ ń mú wá.