-
Àwọn Onídàájọ́ 8:2, 3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Àmọ́ ó sọ fún wọn pé: “Ṣé ohun tí mo ṣe wá tó nǹkan kan lẹ́gbẹ̀ẹ́ tiyín? Ṣé èéṣẹ́ Éfúrémù + ò dáa ju ìkórè èso àjàrà Abi-ésérì lọ ni?+ 3 Ẹ̀yin ni Ọlọ́run fi àwọn ìjòyè Mídíánì, ìyẹn Órébù àti Séébù+ lé lọ́wọ́, ṣé ohun tí mo ṣe wá tó nǹkan kan lẹ́gbẹ̀ẹ́ tiyín?” Nígbà tó sọ̀rọ̀ báyìí,* ara wọn balẹ̀.*
-