ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 32:4, 5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 ó pàṣẹ fún wọn pé: “Ohun tí ẹ máa sọ fún Ísọ̀ olúwa mi nìyí, ‘Ohun tí Jékọ́bù ìránṣẹ́ rẹ sọ nìyí: “Ó ti pẹ́ tí mo ti ń gbé* lọ́dọ̀ Lábánì títí di báyìí.+ 5 Mo ti ní àwọn akọ màlúù, kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́, àgùntàn, àwọn ìránṣẹ́kùnrin àti ìránṣẹ́bìnrin,+ mo sì ń ránṣẹ́ yìí sí olúwa mi láti fi èyí tó o létí, kí n lè rí ojúure rẹ.”’”

  • Òwe 15:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Ìdáhùn pẹ̀lẹ́* máa ń mú kí ìbínú rọlẹ̀,+

      Àmọ́ ọ̀rọ̀ líle* ń ru ìbínú sókè.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́