Òwe 16:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Ọkàn ọlọ́gbọ́n ń fún ẹnu rẹ̀ ní ìjìnlẹ̀ òye+Ó sì ń fi ìyíniléròpadà kún ọ̀rọ̀ rẹ̀. Àìsáyà 50:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ ti fún mi ní ahọ́n àwọn tí a kọ́,*+Kí n lè mọ bó ṣe yẹ kí n fi ọ̀rọ̀ tó yẹ* dá ẹni tó ti rẹ̀ lóhùn.*+ Ó ń jí mi ní àràárọ̀;Ó ń jí etí mi kí n lè fetí sílẹ̀ bí àwọn tí a kọ́.+
4 Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ ti fún mi ní ahọ́n àwọn tí a kọ́,*+Kí n lè mọ bó ṣe yẹ kí n fi ọ̀rọ̀ tó yẹ* dá ẹni tó ti rẹ̀ lóhùn.*+ Ó ń jí mi ní àràárọ̀;Ó ń jí etí mi kí n lè fetí sílẹ̀ bí àwọn tí a kọ́.+