Òwe 9:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Má ṣe bá afiniṣẹ̀sín wí, torí á kórìíra rẹ.+ Bá ọlọ́gbọ́n wí, yóò sì nífẹ̀ẹ́ rẹ.+ Òwe 19:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Fetí sí ìmọ̀ràn kí o sì gba ìbáwí,+Kí o lè di ọlọ́gbọ́n ní ọjọ́ ọ̀la rẹ.+