Diutarónómì 8:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 má ṣe gbéra ga nínú ọkàn rẹ,+ kó sì mú kí o gbàgbé Jèhófà Ọlọ́run rẹ tó mú ọ kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì, kúrò ní ilé ẹrú,+ Diutarónómì 8:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 ó sì fi mánà bọ́ ọ+ nínú aginjù, èyí tí àwọn bàbá rẹ ò mọ̀, kó lè rẹ̀ ọ́ sílẹ̀,+ kó sì dán ọ wò, kó lè ṣe ọ́ láǹfààní lọ́jọ́ ọ̀la.+ Hébérù 12:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ẹ nílò ìfaradà bí ẹ ṣe ń gba ìbáwí.* Ọlọ́run mú yín bí ọmọ.+ Torí ọmọ wo ni bàbá kì í bá wí?+ Hébérù 12:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Lóòótọ́, kò sí ìbáwí tó jẹ́ ohun ayọ̀ báyìí, àmọ́ ó máa ń dunni;* síbẹ̀, tó bá yá, ó máa ń so èso àlàáfíà ti òdodo fún àwọn tí a ti fi dá lẹ́kọ̀ọ́.
14 má ṣe gbéra ga nínú ọkàn rẹ,+ kó sì mú kí o gbàgbé Jèhófà Ọlọ́run rẹ tó mú ọ kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì, kúrò ní ilé ẹrú,+
16 ó sì fi mánà bọ́ ọ+ nínú aginjù, èyí tí àwọn bàbá rẹ ò mọ̀, kó lè rẹ̀ ọ́ sílẹ̀,+ kó sì dán ọ wò, kó lè ṣe ọ́ láǹfààní lọ́jọ́ ọ̀la.+
11 Lóòótọ́, kò sí ìbáwí tó jẹ́ ohun ayọ̀ báyìí, àmọ́ ó máa ń dunni;* síbẹ̀, tó bá yá, ó máa ń so èso àlàáfíà ti òdodo fún àwọn tí a ti fi dá lẹ́kọ̀ọ́.