-
Òwe 6:16, 17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Ojú ìgbéraga,+ ahọ́n èké+ àti ọwọ́ tó ń ta ẹ̀jẹ̀ aláìṣẹ̀ sílẹ̀,+
-
Òwe 21:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Ojú ìgbéraga àti ọkàn gíga
Ni fìtílà tó ń darí àwọn ẹni burúkú, ẹ̀ṣẹ̀ sì ni.+
-
-
-