-
Sáàmù 37:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Ohun díẹ̀ tí olódodo ní
Sàn ju ọ̀pọ̀ nǹkan tí àwọn ẹni burúkú ní.+
-
-
Jeremáyà 17:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Wọ́n á fi í sílẹ̀ ní ọ̀sán gangan ayé rẹ̀,
Ní ìkẹyìn, á wá hàn pé òmùgọ̀ ni.”
-