Òwe 28:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Olóòótọ́ èèyàn yóò gba ọ̀pọ̀ ìbùkún,+Àmọ́ ọwọ́ ẹni tó ń kánjú láti di olówó kò lè mọ́.+ Àìsáyà 1:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Alágídí ni àwọn ìjòyè rẹ, àwọn àtàwọn olè jọ ń ṣiṣẹ́.+ Gbogbo wọn ló fẹ́ràn àbẹ̀tẹ́lẹ̀, wọ́n sì ń wá ẹ̀bùn kiri.+ Wọn kì í dá ẹjọ́ àwọn ọmọ aláìníbaba* bó ṣe tọ́,Ẹjọ́ opó kì í sì í dé iwájú wọn.+ Jémíìsì 5:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Wò ó! Owó iṣẹ́ tí ẹ ò san fún àwọn òṣìṣẹ́ tó kórè oko yín ń ké jáde ṣáá, igbe tí àwọn olùkórè ń ké fún ìrànwọ́ sì ti dé etí Jèhófà* Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun.+
23 Alágídí ni àwọn ìjòyè rẹ, àwọn àtàwọn olè jọ ń ṣiṣẹ́.+ Gbogbo wọn ló fẹ́ràn àbẹ̀tẹ́lẹ̀, wọ́n sì ń wá ẹ̀bùn kiri.+ Wọn kì í dá ẹjọ́ àwọn ọmọ aláìníbaba* bó ṣe tọ́,Ẹjọ́ opó kì í sì í dé iwájú wọn.+
4 Wò ó! Owó iṣẹ́ tí ẹ ò san fún àwọn òṣìṣẹ́ tó kórè oko yín ń ké jáde ṣáá, igbe tí àwọn olùkórè ń ké fún ìrànwọ́ sì ti dé etí Jèhófà* Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun.+