Òwe 16:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Èèyàn lè gbèrò ohun kan lọ́kàn ara rẹ̀,*Àmọ́ ọ̀dọ̀ Jèhófà ni ìdáhùn rẹ̀* ti máa wá.+ Jeremáyà 10:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Jèhófà, mo mọ̀ dáadáa pé ọ̀nà èèyàn kì í ṣe tirẹ̀. Àní kò sí ní ìkáwọ́ èèyàn tó ń rìn láti darí ìṣísẹ̀ ara rẹ̀.+
23 Jèhófà, mo mọ̀ dáadáa pé ọ̀nà èèyàn kì í ṣe tirẹ̀. Àní kò sí ní ìkáwọ́ èèyàn tó ń rìn láti darí ìṣísẹ̀ ara rẹ̀.+