ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Rúùtù 1:16, 17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Àmọ́ Rúùtù sọ pé: “Má rọ̀ mí pé kí n fi ọ́ sílẹ̀, pé kí n má ṣe bá ọ lọ; torí ibi tí o bá lọ ni èmi yóò lọ, ibi tí o bá sùn ni èmi yóò sùn. Àwọn èèyàn rẹ ni yóò jẹ́ èèyàn mi, Ọlọ́run rẹ ni yóò sì jẹ́ Ọlọ́run mi.+ 17 Ibi tí o bá kú sí ni èmi yóò kú sí, ibẹ̀ sì ni wọn yóò sin mí sí. Kí Jèhófà fi ìyà jẹ mí gan-an bí ohunkóhun yàtọ̀ sí ikú bá yà wá.”

  • 1 Sámúẹ́lì 19:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 Nítorí pé Jónátánì ọmọ Sọ́ọ̀lù nífẹ̀ẹ́ Dáfídì+ gan-an, ó sọ fún Dáfídì pé: “Sọ́ọ̀lù bàbá mi fẹ́ pa ọ́. Jọ̀wọ́ múra láàárọ̀ ọ̀la, sá lọ sí ibi ìkọ̀kọ̀ kan, kí o sì fara pa mọ́ síbẹ̀.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́