-
Rúùtù 2:11, 12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Bóásì dá a lóhùn pé: “Gbogbo ohun tí o ṣe fún ìyá ọkọ rẹ lẹ́yìn ikú ọkọ rẹ ni wọ́n ti ròyìn fún mi àti bí o ṣe fi bàbá àti ìyá rẹ àti ìlú ìbílẹ̀ rẹ sílẹ̀, tí o sì wá sọ́dọ̀ àwọn èèyàn tí ìwọ kò mọ̀ rí.+ 12 Kí Jèhófà san ẹ̀san ohun tí o ṣe fún ọ,+ kí Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì, ẹni tí o wá ààbò wá sábẹ́ ìyẹ́ apá rẹ̀+ sì fún ọ ní ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ èrè.”
-