ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Òwe 5:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  3 Nítorí ètè obìnrin oníwàkiwà* ń kán tótó bí afárá oyin,+

      Ọ̀rọ̀* rẹ̀ sì tuni lára ju òróró lọ.+

  • Òwe 5:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  5 Àwọn ẹsẹ̀ rẹ̀ lọ sí ikú.

      Àwọn ìṣísẹ̀ rẹ̀ lọ tààrà sí Isà Òkú.*

  • Òwe 5:20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 Torí náà, ọmọ mi, kí nìdí tí wàá fi jẹ́ kí obìnrin oníwàkiwà* gbà ọ́ lọ́kàn

      Tàbí tí wàá fi gbá àyà obìnrin oníṣekúṣe* mọ́ra?+

  • Òwe 5:23
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 23 Ó máa kú nítorí kò gba ìbáwí

      Á sì ṣìnà nítorí ìwà òmùgọ̀ rẹ̀ tó pọ̀ lápọ̀jù.

  • Òwe 9:16-18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 “Kí ẹni tó bá jẹ́ aláìmọ̀kan wọlé síbí.”

      Ó sọ fún àwọn tí kò ní làákàyè* pé:+

      17 “Omi tí a jí gbé máa ń dùn,

      Oúnjẹ tí a sì jẹ ní ìkọ̀kọ̀ máa ń gbádùn mọ́ni.”+

      18 Àmọ́ wọn kò mọ̀ pé àwọn tí ikú ti pa* wà níbẹ̀,

      Àti pé àwọn àlejò rẹ̀ wà ní ìsàlẹ̀ Isà Òkú.*+

  • Éfésù 5:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Nítorí ẹ mọ èyí, ó sì ṣe kedere sí ẹ̀yin fúnra yín, pé kò sí oníṣekúṣe* kankan+ tàbí aláìmọ́ tàbí olójúkòkòrò,+ tó túmọ̀ sí jíjẹ́ abọ̀rìṣà, tí ó ní ogún èyíkéyìí nínú Ìjọba Kristi àti ti Ọlọ́run.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́