ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Òwe 2:18, 19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Nítorí ilé rẹ̀ ń rini sínú ikú,

      Àwọn ọ̀nà* rẹ̀ sì lọ sọ́dọ̀ àwọn tí ikú ti pa.*+

      19 Kò sí ìkankan lára àwọn tó ní ohunkóhun ṣe pẹ̀lú rẹ̀* tó máa pa dà,

      Bẹ́ẹ̀ ni wọn ò ní pa dà sí ọ̀nà ìyè.+

  • Òwe 7:23
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 23 Títí ọfà fi gún ẹ̀dọ̀ rẹ̀ ní àgúnyọ;

      Bí ẹyẹ tó kó sínú pańpẹ́, kò mọ̀ pé ẹ̀mí òun máa lọ sí i.+

  • Òwe 7:26
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 26 Nítorí ọ̀pọ̀ èèyàn ló ti ṣekú pa,+

      Àwọn tó ti pa sì pọ̀ gan-an.+

  • Òwe 23:27, 28
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 27 Nítorí pé kòtò jíjìn ni aṣẹ́wó,

      Kànga tóóró sì ni obìnrin oníṣekúṣe.*+

      28 Ó máa ń lúgọ deni bí ọlọ́ṣà;+

      Ó ń mú kí àwọn ọkùnrin aláìṣòótọ́ pọ̀ sí i.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́