Oníwàásù 2:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Ojú ọlọ́gbọ́n wà ní orí rẹ̀;*+ àmọ́ òmùgọ̀ ń rìn nínú òkùnkùn.+ Mo sì wá rí i pé ohun* kan náà ló ń ṣẹlẹ̀ sí gbogbo wọn.+
14 Ojú ọlọ́gbọ́n wà ní orí rẹ̀;*+ àmọ́ òmùgọ̀ ń rìn nínú òkùnkùn.+ Mo sì wá rí i pé ohun* kan náà ló ń ṣẹlẹ̀ sí gbogbo wọn.+