Òwe 14:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ọgbọ́n ni aláròjinlẹ̀ fi ń lóye ibi tí ọ̀nà rẹ̀ máa já sí,Àmọ́ ìwà ẹ̀gọ̀ àwọn òmùgọ̀ ló ń ṣì wọ́n lọ́nà.*+ Òwe 17:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Ọgbọ́n wà ní ọ̀gangan iwájú olóye,Àmọ́ ojú àwọn òmùgọ̀ ń rìn gbéregbère títí dé ìkángun ayé.+ Jòhánù 3:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ohun tí a máa gbé ìdájọ́ kà nìyí: pé ìmọ́lẹ̀ ti wá sí ayé,+ àmọ́ àwọn èèyàn nífẹ̀ẹ́ òkùnkùn dípò ìmọ́lẹ̀, torí pé oníṣẹ́ ibi ni wọ́n. 1 Jòhánù 2:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Àmọ́ ẹni tó bá kórìíra arákùnrin rẹ̀ wà nínú òkùnkùn, ó ń rìn nínú òkùnkùn,+ kò sì mọ ibi tó ń lọ,+ torí òkùnkùn ò jẹ́ kó ríran.
8 Ọgbọ́n ni aláròjinlẹ̀ fi ń lóye ibi tí ọ̀nà rẹ̀ máa já sí,Àmọ́ ìwà ẹ̀gọ̀ àwọn òmùgọ̀ ló ń ṣì wọ́n lọ́nà.*+
19 Ohun tí a máa gbé ìdájọ́ kà nìyí: pé ìmọ́lẹ̀ ti wá sí ayé,+ àmọ́ àwọn èèyàn nífẹ̀ẹ́ òkùnkùn dípò ìmọ́lẹ̀, torí pé oníṣẹ́ ibi ni wọ́n.
11 Àmọ́ ẹni tó bá kórìíra arákùnrin rẹ̀ wà nínú òkùnkùn, ó ń rìn nínú òkùnkùn,+ kò sì mọ ibi tó ń lọ,+ torí òkùnkùn ò jẹ́ kó ríran.