Òwe 15:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ọlọ́gbọ́n ọmọ máa ń mú inú bàbá rẹ̀ dùn,+Àmọ́ òmùgọ̀ èèyàn máa ń kórìíra ìyá rẹ̀.+