Òwe 23:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Fetí sí bàbá rẹ tó bí ọ lọ́mọ,Má sì pa ìyá rẹ tì torí pé ó ti darúgbó.+ Òwe 30:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ojú tó ń fi bàbá ṣẹ̀sín, tí kì í sì í ṣègbọràn sí ìyá,+Àwọn ẹyẹ ìwò tó wà ní àfonífojì yóò yọ ọ́ jáde,Àwọn ọmọ ẹyẹ idì yóò sì mú un jẹ.+
17 Ojú tó ń fi bàbá ṣẹ̀sín, tí kì í sì í ṣègbọràn sí ìyá,+Àwọn ẹyẹ ìwò tó wà ní àfonífojì yóò yọ ọ́ jáde,Àwọn ọmọ ẹyẹ idì yóò sì mú un jẹ.+