Sáàmù 37:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Àmọ́ àwọn oníwà pẹ̀lẹ́ ni yóò jogún ayé,+Inú wọn yóò sì máa dùn jọjọ nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ àlàáfíà.+ Sáàmù 37:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Àwọn olódodo ni yóò jogún ayé,+Wọn yóò sì máa gbé inú rẹ̀ títí láé.+