Diutarónómì 30:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 nípa nínífẹ̀ẹ́ Jèhófà Ọlọ́run+ rẹ, kí o máa fetí sí ohùn rẹ̀, kí o sì rọ̀ mọ́ ọn,+ torí òun ni ìyè rẹ, òun ló sì máa mú kí o pẹ́ lórí ilẹ̀ tí Jèhófà búra pé òun máa fún àwọn baba ńlá rẹ Ábúráhámù, Ísákì àti Jékọ́bù.”+ Sáàmù 37:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Nítorí a ó mú àwọn ẹni ibi kúrò,+Àmọ́ àwọn tó gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà ni yóò jogún ayé.+ Òwe 2:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Nítorí àwọn adúróṣinṣin ló máa gbé ní ayé,Àwọn aláìlẹ́bi* ló sì máa ṣẹ́ kù sínú rẹ̀.+ Mátíù 5:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 “Aláyọ̀ ni àwọn oníwà tútù,*+ torí wọ́n máa jogún ayé.+
20 nípa nínífẹ̀ẹ́ Jèhófà Ọlọ́run+ rẹ, kí o máa fetí sí ohùn rẹ̀, kí o sì rọ̀ mọ́ ọn,+ torí òun ni ìyè rẹ, òun ló sì máa mú kí o pẹ́ lórí ilẹ̀ tí Jèhófà búra pé òun máa fún àwọn baba ńlá rẹ Ábúráhámù, Ísákì àti Jékọ́bù.”+