Sáàmù 104:35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 Àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ yóò pa rẹ́ kúrò láyé,Àwọn ẹni burúkú kò sì ní sí mọ́.+ Jẹ́ kí n* yin Jèhófà. Ẹ yin Jáà!* Òwe 10:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ìrántí* olódodo yẹ fún ìbùkún,+Àmọ́ orúkọ àwọn ẹni burúkú yóò jẹrà.+ Mátíù 25:46 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 46 Àwọn yìí máa lọ sínú ìparun* àìnípẹ̀kun,+ ṣùgbọ́n àwọn olódodo sínú ìyè àìnípẹ̀kun.”+
35 Àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ yóò pa rẹ́ kúrò láyé,Àwọn ẹni burúkú kò sì ní sí mọ́.+ Jẹ́ kí n* yin Jèhófà. Ẹ yin Jáà!*