Diutarónómì 19:18, 19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Kí àwọn adájọ́ náà wádìí ọ̀rọ̀ náà dáadáa,+ tó bá jẹ́ ẹlẹ́rìí èké ni ẹni tó jẹ́rìí sí ọ̀rọ̀ náà, tó sì fẹ̀sùn èké kan arákùnrin rẹ̀, 19 ohun tó gbèrò láti ṣe sí arákùnrin rẹ̀ ni kí ẹ ṣe sí i,+ kí ẹ sì mú ohun tó burú kúrò láàárín yín.+
18 Kí àwọn adájọ́ náà wádìí ọ̀rọ̀ náà dáadáa,+ tó bá jẹ́ ẹlẹ́rìí èké ni ẹni tó jẹ́rìí sí ọ̀rọ̀ náà, tó sì fẹ̀sùn èké kan arákùnrin rẹ̀, 19 ohun tó gbèrò láti ṣe sí arákùnrin rẹ̀ ni kí ẹ ṣe sí i,+ kí ẹ sì mú ohun tó burú kúrò láàárín yín.+