Òwe 19:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ìrunú ọba dà bí ìgbà tí kìnnìún* bá ń kùn,+Àmọ́ ojú rere rẹ̀ dà bí ìrì lára ewéko. Oníwàásù 10:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Tí inú* alákòóso bá ru sí ọ, má ṣe kúrò níbi tí o wà,+ torí pé ìwà pẹ̀lẹ́ ń pẹ̀tù sí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ ńlá.+
4 Tí inú* alákòóso bá ru sí ọ, má ṣe kúrò níbi tí o wà,+ torí pé ìwà pẹ̀lẹ́ ń pẹ̀tù sí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ ńlá.+