Òwe 22:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ọkàn ọmọdé* ni ìwà òmùgọ̀ dì sí,+Àmọ́ ọ̀pá ìbáwí yóò mú un jìnnà sí i.+