Òwe 13:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Ẹni tó bá fa ọ̀pá* sẹ́yìn kórìíra ọmọ rẹ̀,+Àmọ́ ẹni tó bá nífẹ̀ẹ́ ọmọ rẹ̀ máa ń bá a wí dáadáa.*+ Òwe 19:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Bá ọmọ rẹ wí nígbà tí ìrètí ṣì wà,+Kí o má bàa jẹ̀bi* ikú rẹ̀.+