ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Òwe 11:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Nígbà tí kò bá sí ìtọ́sọ́nà ọlọgbọ́n, àwọn èèyàn á ṣubú,

      Àmọ́ nípasẹ̀ ọ̀pọ̀ agbani-nímọ̀ràn,* àṣeyọrí* á wà.+

  • Òwe 24:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  6 Ìtọ́sọ́nà ọlọgbọ́n ni kí o fi ja ogun rẹ,+

      Nípasẹ̀ ọ̀pọ̀ agbani-nímọ̀ràn,* ìṣẹ́gun* á wà.+

  • Lúùkù 14:31, 32
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 31 Àbí ọba wo, tó fẹ́ lọ bá ọba míì jagun, ni kò ní kọ́kọ́ jókòó, kó sì gba ìmọ̀ràn láti mọ̀ bóyá òun máa lè fi ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá (10,000) ọmọ ogun gbéjà ko ẹni tó ń kó ẹgbẹ̀rún lọ́nà ogún (20,000) bọ̀ wá bá a jà? 32 Ní tòótọ́, tí kò bá lè ṣe bẹ́ẹ̀, á jẹ́ pé nígbà tí ọ̀nà ẹni yẹn ṣì jìn, ó máa rán àwọn ikọ̀ lọ, á sì bẹ̀bẹ̀ fún àlàáfíà.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́