-
Òwe 25:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Ro ẹjọ́ rẹ pẹ̀lú ọmọnìkejì rẹ,+
Àmọ́ má sọ ọ̀rọ̀ àṣírí tí o gbọ́,*+
-
Òwe 25:23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 Ẹ̀fúùfù láti àríwá ń mú kí òjò rọ̀,
Ahọ́n tó ń ṣòfófó sì ń mú kí ojú fà ro.+
-
-
-