Sáàmù 34:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Áńgẹ́lì Jèhófà pàgọ́ yí àwọn tó bẹ̀rù Rẹ̀ ká,+Ó sì ń gbà wọ́n sílẹ̀.+ 1 Pétérù 4:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Nítorí náà, kí àwọn tó ń jìyà lọ́nà tó bá ìfẹ́ Ọlọ́run mu máa fi ara* wọn lé Ẹlẹ́dàá tó jẹ́ olóòótọ́ lọ́wọ́,* kí wọ́n sì máa ṣe rere.+
19 Nítorí náà, kí àwọn tó ń jìyà lọ́nà tó bá ìfẹ́ Ọlọ́run mu máa fi ara* wọn lé Ẹlẹ́dàá tó jẹ́ olóòótọ́ lọ́wọ́,* kí wọ́n sì máa ṣe rere.+