Òwe 17:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Òkèlè* gbígbẹ níbi tí àlàáfíà wà*+Sàn ju ilé àsè* rẹpẹtẹ tí ìjà wà.+ Òwe 21:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ó sàn láti máa gbé ní aginjùJu kéèyàn máa bá aya tó jẹ́ oníjà* àti oníkanra gbé.+ Òwe 25:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Ó sàn láti máa gbé ní igun òrùléJu kéèyàn máa bá aya tó jẹ́ oníjà* gbé inú ilé kan náà.+ Òwe 27:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Aya tó jẹ́ oníjà* dà bí òrùlé tó ń jò ṣùrùṣùrù lọ́jọ́ tí òjò ń rọ̀.+