Òwe 21:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ó sàn láti máa gbé ní igun òrùléJu kéèyàn máa bá aya tó jẹ́ oníjà* gbé inú ilé kan náà.+ Òwe 21:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ó sàn láti máa gbé ní aginjùJu kéèyàn máa bá aya tó jẹ́ oníjà* àti oníkanra gbé.+