Sáàmù 111:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ìbẹ̀rù Jèhófà ni ìbẹ̀rẹ̀ ọgbọ́n.+ ש [Sínì] Gbogbo àwọn tó ń pa àwọn àṣẹ rẹ̀* mọ́ ní òye tó jinlẹ̀ gan-an.+ ת [Tọ́ọ̀] Ìyìn rẹ̀ wà títí láé. 2 Kọ́ríńtì 7:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Nítorí náà, ẹ̀yin ẹni ọ̀wọ́n, nígbà tí a ti gba àwọn ìlérí yìí,+ ẹ jẹ́ kí a wẹ ara wa mọ́ kúrò nínú gbogbo ẹ̀gbin ti ara àti ti ẹ̀mí,+ kí a jẹ́ mímọ́ pátápátá nínú ìbẹ̀rù Ọlọ́run.
10 Ìbẹ̀rù Jèhófà ni ìbẹ̀rẹ̀ ọgbọ́n.+ ש [Sínì] Gbogbo àwọn tó ń pa àwọn àṣẹ rẹ̀* mọ́ ní òye tó jinlẹ̀ gan-an.+ ת [Tọ́ọ̀] Ìyìn rẹ̀ wà títí láé.
7 Nítorí náà, ẹ̀yin ẹni ọ̀wọ́n, nígbà tí a ti gba àwọn ìlérí yìí,+ ẹ jẹ́ kí a wẹ ara wa mọ́ kúrò nínú gbogbo ẹ̀gbin ti ara àti ti ẹ̀mí,+ kí a jẹ́ mímọ́ pátápátá nínú ìbẹ̀rù Ọlọ́run.