Sáàmù 26:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Mo kórìíra àwùjọ àwọn aṣebi,+Mi ò sì jẹ́ bá àwọn ẹni burúkú kẹ́gbẹ́.*+ Òwe 1:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ọmọ mi, tí àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ bá fẹ́ fa ojú rẹ mọ́ra, má gbà.+