Òwe 14:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ẹlẹ́gàn ń wá ọgbọ́n, kò sì rí i,Àmọ́ ìmọ̀ máa ń wá sọ́dọ̀ àwọn olóye pẹ̀lú ìrọ̀rùn.+ 1 Kọ́ríńtì 2:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Ẹni ti ara kì í tẹ́wọ́ gba* àwọn nǹkan ti ẹ̀mí Ọlọ́run, torí wọ́n jẹ́ nǹkan òmùgọ̀ lójú rẹ̀; kò sì lè mọ̀ wọ́n, nítorí ẹ̀mí la fi ń wádìí wọn.
14 Ẹni ti ara kì í tẹ́wọ́ gba* àwọn nǹkan ti ẹ̀mí Ọlọ́run, torí wọ́n jẹ́ nǹkan òmùgọ̀ lójú rẹ̀; kò sì lè mọ̀ wọ́n, nítorí ẹ̀mí la fi ń wádìí wọn.