ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Àwọn Ọba 2:44
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 44 Lẹ́yìn náà, ọba sọ fún Ṣíméì pé: “Nínú ọkàn rẹ, o mọ gbogbo jàǹbá tí o ṣe fún Dáfídì bàbá mi,+ Jèhófà yóò sì dá jàǹbá náà pa dà sórí rẹ.+

  • 1 Àwọn Ọba 2:46
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 46 Ni ọba bá pàṣẹ fún Bẹnáyà ọmọ Jèhóádà, Bẹnáyà jáde lọ, ó ṣá a balẹ̀, ó sì kú.+

      Bí ìjọba náà ṣe fìdí múlẹ̀ gbọn-in lọ́wọ́ Sólómọ́nì nìyẹn.+

  • Òwe 20:28
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 28 Ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ àti òtítọ́ ń dáàbò bo ọba;+

      Ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ sì ń jẹ́ kó pẹ́ lórí ìtẹ́ rẹ̀.+

  • Òwe 29:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Tí ọba bá ń ṣe ìdájọ́ àwọn aláìní bó ṣe tọ́,+

      Ìtẹ́ rẹ̀ á fìdí múlẹ̀ títí lọ.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́