Òwe 15:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Ojú tó ń dán* máa ń mú ọkàn yọ̀;Ìròyìn tó dára máa ń mú kí egungun lágbára.*+ Àìsáyà 52:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Wo bí ẹsẹ̀ ẹni tó ń mú ìhìn rere wá ṣe rẹwà tó lórí àwọn òkè,+Ẹni tó ń kéde àlàáfíà,+Ẹni tó ń mú ìhìn rere wá nípa ohun tó sàn,Ẹni tó ń kéde ìgbàlà,Ẹni tó ń sọ fún Síónì pé: “Ọlọ́run rẹ ti di Ọba!”+
7 Wo bí ẹsẹ̀ ẹni tó ń mú ìhìn rere wá ṣe rẹwà tó lórí àwọn òkè,+Ẹni tó ń kéde àlàáfíà,+Ẹni tó ń mú ìhìn rere wá nípa ohun tó sàn,Ẹni tó ń kéde ìgbàlà,Ẹni tó ń sọ fún Síónì pé: “Ọlọ́run rẹ ti di Ọba!”+