Òwe 15:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Ẹni tí kò ní làákàyè* máa ń fi ìwà òmùgọ̀ ṣayọ̀,+Àmọ́ ẹni tó ní òye máa ń rìn lọ tààrà.+