Léfítíkù 19:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 “‘O ò gbọ́dọ̀ kórìíra arákùnrin rẹ nínú ọkàn rẹ.+ Kí o rí i pé o bá ẹnì kejì rẹ wí,+ kí o má bàa jẹ nínú ìyà ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀. Mátíù 18:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 “Bákan náà, tí arákùnrin rẹ bá ṣẹ̀, lọ sọ ẹ̀bi rẹ̀ fún un* láàárín ìwọ àti òun nìkan.+ Tó bá fetí sí ọ, o ti jèrè arákùnrin rẹ.+
17 “‘O ò gbọ́dọ̀ kórìíra arákùnrin rẹ nínú ọkàn rẹ.+ Kí o rí i pé o bá ẹnì kejì rẹ wí,+ kí o má bàa jẹ nínú ìyà ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀.
15 “Bákan náà, tí arákùnrin rẹ bá ṣẹ̀, lọ sọ ẹ̀bi rẹ̀ fún un* láàárín ìwọ àti òun nìkan.+ Tó bá fetí sí ọ, o ti jèrè arákùnrin rẹ.+