1 Sámúẹ́lì 23:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Ni Jónátánì ọmọ Sọ́ọ̀lù bá lọ sọ́dọ̀ Dáfídì ní Hóréṣì, ó sì ràn án lọ́wọ́ kí ó lè túbọ̀ gbẹ́kẹ̀ lé* Jèhófà.+ Hébérù 10:24, 25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Ẹ sì jẹ́ ká gba ti ara wa rò* ká lè máa fún ara wa níṣìírí* láti ní ìfẹ́ àti láti ṣe àwọn iṣẹ́ rere,+ 25 ká má ṣe máa kọ ìpàdé wa sílẹ̀,+ bí àṣà àwọn kan, àmọ́ ká máa gba ara wa níyànjú,+ ní pàtàkì jù lọ bí ẹ ṣe ń rí i pé ọjọ́ náà ń sún mọ́lé.+
16 Ni Jónátánì ọmọ Sọ́ọ̀lù bá lọ sọ́dọ̀ Dáfídì ní Hóréṣì, ó sì ràn án lọ́wọ́ kí ó lè túbọ̀ gbẹ́kẹ̀ lé* Jèhófà.+
24 Ẹ sì jẹ́ ká gba ti ara wa rò* ká lè máa fún ara wa níṣìírí* láti ní ìfẹ́ àti láti ṣe àwọn iṣẹ́ rere,+ 25 ká má ṣe máa kọ ìpàdé wa sílẹ̀,+ bí àṣà àwọn kan, àmọ́ ká máa gba ara wa níyànjú,+ ní pàtàkì jù lọ bí ẹ ṣe ń rí i pé ọjọ́ náà ń sún mọ́lé.+