Sáàmù 37:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Fi ọ̀nà rẹ lé Jèhófà lọ́wọ́;*+Gbẹ́kẹ̀ lé e, yóò sì gbé ìgbésẹ̀ nítorí rẹ.+ Òwe 17:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ọ̀rẹ́ tòótọ́ máa ń nífẹ̀ẹ́ ẹni nígbà gbogbo,+Ó sì jẹ́ ọmọ ìyá tí a bí fún ìgbà wàhálà.+