-
1 Àwọn Ọba 16:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Ní ọdún kẹrìndínlọ́gbọ̀n Ásà ọba Júdà, Élà ọmọ Bááṣà di ọba lórí Ísírẹ́lì ní Tírísà, ọdún méjì ló sì fi ṣàkóso.
-
-
1 Àwọn Ọba 16:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Ní ọdún kẹtàdínlọ́gbọ̀n Ásà ọba Júdà, Símírì di ọba ní Tírísà, ọjọ́ méje ló sì fi jọba nígbà tí àwọn ọmọ ogun dó ti Gíbétónì,+ tó jẹ́ ti àwọn Filísínì.
-
-
1 Àwọn Ọba 16:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 Àmọ́, àwọn èèyàn tó tẹ̀ lé Ómírì borí àwọn tó tẹ̀ lé Tíbínì ọmọ Gínátì. Torí náà, Tíbínì kú, Ómírì sì di ọba.
-