ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Òwe 5:8-10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  8 Jìnnà réré sí i;

      Má sì sún mọ́ ẹnu ọ̀nà ilé rẹ̀,+

       9 Kí o má bàa fi iyì rẹ fún àwọn ẹlòmíì+

      Tàbí kí o fi ọ̀pọ̀ ọdún kórè ohun tó burú;+

      10 Kí àwọn àjèjì má bàa fa ọrọ̀* rẹ gbẹ,+

      Kí àwọn ohun tí o ṣiṣẹ́ kára fún sì lọ sí ilé àjèjì.

  • Òwe 6:26
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 26 Ní tìtorí aṣẹ́wó, èèyàn á di ẹni tí kò ní ju búrẹ́dì kan ṣoṣo lọ,+

      Ní ti obìnrin alágbèrè, ẹ̀mí* tó ṣeyebíye ló fi ń ṣe ìjẹ.

  • Lúùkù 15:13, 14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Lẹ́yìn ọjọ́ mélòó kan, èyí àbúrò kó gbogbo ohun tó jẹ́ tirẹ̀ jọ, ó sì rìnrìn àjò lọ sí ilẹ̀ tó jìnnà gan-an, ibẹ̀ ló ti ń gbé ìgbésí ayé oníwà pálapàla,* tó sì lo àwọn ohun ìní rẹ̀ nílòkulò. 14 Nígbà tó ti ná gbogbo rẹ̀ tán, ìyàn mú gan-an ní gbogbo ilẹ̀ yẹn, ó sì di aláìní.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́