1 Sámúẹ́lì 18:8, 9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Inú bí Sọ́ọ̀lù gan-an,+ orin yìí sì bà á lọ́kàn jẹ́, ó sọ pé: “Wọ́n fún Dáfídì ní ẹgbẹẹgbàárùn-ún, àmọ́ wọ́n fún mi ní ẹgbẹẹgbẹ̀rún. Ipò ọba nìkan ló kù kí wọ́n fún un!”+ 9 Láti ọjọ́ yẹn lọ, ìgbà gbogbo ni Sọ́ọ̀lù ń wo Dáfídì tìfuratìfura. Jémíìsì 3:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Torí ibikíbi tí wọ́n bá ti ń jowú tí wọ́n sì ń fa ọ̀rọ̀,* ìdàrúdàpọ̀ àti gbogbo nǹkan burúkú máa ń wà níbẹ̀.+
8 Inú bí Sọ́ọ̀lù gan-an,+ orin yìí sì bà á lọ́kàn jẹ́, ó sọ pé: “Wọ́n fún Dáfídì ní ẹgbẹẹgbàárùn-ún, àmọ́ wọ́n fún mi ní ẹgbẹẹgbẹ̀rún. Ipò ọba nìkan ló kù kí wọ́n fún un!”+ 9 Láti ọjọ́ yẹn lọ, ìgbà gbogbo ni Sọ́ọ̀lù ń wo Dáfídì tìfuratìfura.
16 Torí ibikíbi tí wọ́n bá ti ń jowú tí wọ́n sì ń fa ọ̀rọ̀,* ìdàrúdàpọ̀ àti gbogbo nǹkan burúkú máa ń wà níbẹ̀.+